Ebiniseri, itumo eyi ti se, titi de hin hin l’oluwa ranwa lowo de
Ekiti Anglican Diocese yin Oluwa
Fun ewa, iwa mimo ati’fe ara
Tiko l’abawon, tiko l’abuku
K’ama a wa ire ati tesiwaju
Daiosisi wa, l’ola Oluwa Ekiti Anglican Daiosis
Koni t’owo mi baje, kosi ni towo mi daru
Composed By: ???????
Arranged By: ???????